- Artist name: Shoday & BhadBoi OML
- Title: OBT Lyrics
- Release year: 2026
Shoday & BhadBoi OML – OBT Lyrics
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi
Oh, my maye, ma ma ko hun mi
One big transaction, to ma change story mi
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ jọ̀ọ́r dọ̀ mi
(Ob—, Obah)
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (Ob—, Obah)
Oh my maye, ma ma ko hun mi (Wah dem a say?)
One big transaction, to ma change story mi
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ jọ̀ọ́r dọ̀ mi
Wọ ni Naija shi ma dun, but you dey America
E go better la ti n dollar, t’aye Abacha
Owó t’ọmọde bá kọ́ rí, á fi jẹ akara
If I see first money, mo máa sálọ Canada
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (Shoday, kí lo dé?)
Oh, my maye, ma ma ko hun mi
One big transaction, to ma change story mi
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ dọ̀r’dọ̀ mi (Oh, babá yè)
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (Dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma ko hun mi (Ma ma ko hun mi)
One big transaction, to ma change story mi (Ehn)
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ jọ̀ọ́r dọ̀ mi (Oh, babá yè)
Ibí e ní gbégbé kò máa gbé, ìbí ẹ̀ ló máa gbé (Ibí ẹ̀ ló máa gbé)
Ọjà to ni gbégbé kò máa gbé, gbogbo ẹ̀ ló máa gbé (Gbogbo ẹ̀ ló máa gbé)
Purple Haze ninu brown rizzler, high me my canister
O ma ma yè yè yè, wá gbé mi trábàyé, yè, yè
Ayy, it’s going, it’s going, olo mi kò ní sọ̀ ṣí, kò ní sọ̀fọ́
They’re trolling their father
I’m stoning pẹ̀lú kpólí, pẹ̀lú kọ́kọ́
Kò sí problem, kò sí yawà
Kò sí story, kò sí glory, ọmọ ọlọ́gọ́
Ah, dorime fún ọmọ ọpẹ́ (Dorime fún ọmọ ọpẹ́)
Ọmọ oro mi wá pẹ̀ (Ọmọ oro mi wá pẹ̀)
Oh, babá yè
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (Dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma ko hun mi (Ma ma ko hun mi)
One big transaction, to ma change story mi (Ehn)
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ jọ̀ọ́r dọ̀ mi (Oh, babá yè)
Oh, babá yè
Oh, babá yè, dáhùn sọ̀rọ̀ mi (Dáhùn sọ̀rọ̀ mi)
Oh, my maye, ma ma ko hun mi (Ma ma ko hun mi)
One big transaction, to ma change story mi (Ehn)
Màláìkà tó ń pínrẹ́, jọ̀ọ́r wá gbérẹ jọ̀ọ́r dọ̀ mi
Do you find Meevic useful? Click here to give us five stars rating!