Bode Afolabi – Awa Yin O Olorun Lyrics

Awa Yin O Olorun Lyrics by Bode Afolabi

Bode Afolabi - Awa Yin O Olorun Lyrics
  • Artist name: Bode Afolabi
  • Title: Awa Yin O Olorun
  • Release year: 2019

Bode Afolabi – Awa Yin O Olorun Lyrics

Awa Yin O, Olorun

Awa njewo Re pe iwo ni oluwa

Gbgbo aye fi ori ba le fun o

Baba Aye titi lai

Iwo ni eniti gbobo awon Angeli

Nki gbe pe

Orun ati gbogbo agbara

Ti mbe ninu won

Iwo ni eniti awon Kerubu ati awon Serafu

Kigbe pe ni gba gbogbo pe.

Mimo Mimo Mimo

Oluwa Olorun awon omo ogun

Orun oun aiye

Kun fun ola nla ti o go Re

Egbe awon Aposteli

Ti o logo Yin o

Ogba awon Woli

Ti o dara, Yin o

Ogun awon Matyr

Ti o dara Yin o

Ijo Mimo eniyan Olorun

Ni gbogbo aye Nje wo o Re

Baba en ola nla

Ti Ko ni i pe kun

Ati Omo Re nikansoso

Olo la O lo ‘to

Emi Mi mo pelu

Olutunu ni

Kristi, iwo ni Oba Ogo

Iwo ni Omo lailai ti Baba

Nigbati iwo tewogba fun ara Re lati gba eniyan la

O ko korira inu wundia

Nigbati o segun oro iku tan

O si ijoba orun sile fun gbobo

Awon onigbagbo

O jojo ni owo otun Olorun

Ninu Ogo ti Baba

Awa gbagbo pe O mbo wa

Lati se Onidajo wa

Nitorinaa ni awa se ngbadura

Si odo Re

Ran awon omo odo Re lowo

Ti iwo ti fi eje Re

Iyebiye ra pa da

Se won ki a le ka won kun awon eniyan Mimo Re

Ninu ogo Ti ko ni pe kun

Oluwa gba awon eniyan Re la

Ki iwo ki o si fi Ibukun fun awon eniyan i ni Re

J’ O ba won

Ki o si ma gbe won leke lailai

Awa ngbe o ga

Ni o jo jumo

Awon si nfi ori bale ni

Oru ko Re

Titi aye ti ko ni pe kun

Fiyesini Oluwa

Lati pa wa mo loni ni ailese

Oluwa Sanu fun wa

Sa a nu fun wa

Oluwa, je ki anu Re ki o ma ba le wa

Gegebi awa ti n gbeke wa le o

Oluwa, Iwo ni mo Gbe ke le,

Lai, ma je kin da mu

Do you find Meevic useful? Click here to give us five stars rating!

YOU MAY LIKE

  1. No related posts found.

Drop Your Comment (0)

No comments yet, be the first to comment!